Back to sender spell(Ayajo agbelepota todaju)
Use Iyereosun to imprint odu ika meji on any flat tray and chant this spell on it...
Arapanika
Okoko ni kase
Ikani kaja
Obiri biri ta won ji Awo osan
Eriwo ji wo Awo oru
Adanran ma dan olona ofun aasan
Ojiyan ogede niku omo Olofin
Opera lorugba epe waye
Awon mejejo yi lombe lotu Ife
Ise omo olomon pipa je ni won n se
Orunmila gbera oni ohun nlo si Otu Ife
Won ni ki o malo,
Oni nitrori kini
Won ni tori awon Awo mejejo ti mbe lotu Ife
To je pe ise omo olomo pipa je ni won nse
Orunmila ni ohun alo
Won ni ko rubo
Orunmila rubo
Ebo fin ebo da
Orunmila gbera ode Otu Ife
Oni eyin Ife Odaye e o ji re bi ?
Oni Arapanika nko
Won ni ibi ini o gbe ka ,apa re ti kan oti ku
Oni Okoko ni kase nko?
Won ni ibi ti gbe n ka ese, ese re ti kan otiku
Oni Obiribiri ta wonji wonji Awo osan nko?
Won ni otiba awo osan lo,o ti ku
Oni Eriwo jiwo awo oru nko?
Won ni Otiba Awo oru lo ,oti ku
Oni adarandan madan olofun aasan nko?
Won ni otipe aasan re ,ona ofun re ti be, oti ku
Oni ojiyan ogede ni kun omo olofin nko?
Won ni oti pe ogede re ,ikun re ti be, otiku
Oni Opera to ru igba epe waye nko?
Won ni oti se epe re ofa epe re to bolu lese otiku
Orunmila ni bi o ba se ni temi ( a o daruko wa)
Ibi tutu laba rinrin
Ibi tutu laba odundun
Ibi tutu laba tete
Ile igbin ki gbona mo igbin lara
Ki gbogbo ohun t iota fe fi bami ja ki o da tutu
Ki gbogbo ete buburu da pada sori ota
After this spell, you mixed it with a glass of water and drink. No evil spell will hurt you.
Ewe and Egbo, The philosophical exploration of African traditional beliefs. The alignment of nature, science and philosophy for the development of human life.
Thursday, 17 December 2020
SPELL AGAINST EVEIL DOWERS. Back to sender spell.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
THE TRUTH OF IFA
This is a benevolence univese om this ifa says: A tree knot fears no rain Cast Ifa for OLODUMARE AGOTUN The ruler who created the well bala...
-
ASEJE AWURE IRETE ALAJE TODAJU Odidi akuko adie funfun, ewe ina, ewe inabiri, ewe esisi, ewe aragba, ewe oloyin, ata ijosi, aolo papo aofis...
-
This is a benevolence univese om this ifa says: A tree knot fears no rain Cast Ifa for OLODUMARE AGOTUN The ruler who created the well bala...
-
Imi ojo, ewe ejinrin wewe, ewe isaju, ewe oyin, eyin adiye 1, ewe aje Aogun papo pelu ose dudu, aofi imi ojo tefa ose meji sori opon ifa r...
No comments:
Post a Comment