ASEJE AWURE IRETE ALAJE TODAJU
Odidi akuko adie funfun, ewe ina, ewe inabiri, ewe esisi, ewe aragba, ewe oloyin, ata ijosi, aolo papo aofise akouko adie yi je lepo niyo, isasun tuntun laofise, aoso si ori osuka,aofi iyere osun te ifa irete alaje.
Ofore.....
Isan lawo erefe3x arobo lawo aijeun sun, alawo iyo nisawo ajegbin je karawun, awon ni won sefa fun ogberi okunrin tiwonpe ifa ni opuro, odifa fun ogberi obinrin tinpe esu ni yangi, orunmila sewon sila-sila, sewon siba-sibo wa bami, suna-suna lomode roko idi ina, kankan lewe ina jomo, warawara ni omode toko esisi bo, ile kogba won ona kogbawon lose ewe araagba, ojoti omode ba jawe oloyin aye, ojo na lonja tode orun, ojoti won bada iru ekun owo nlanla niwon finru ebo re loju opon, orunmila fi ona ile mi han olowo,oloro ileyii, bi akuko bako,afi ona han awon alejo.
Adua
Aoda iyere osun na sinu aseje naa,aowaro po aoje
Note, gbogbo egungun re aoni run oo,aodasinu isasun naa, aoda awon ewe yen si, aofi odidi atare kan si aojopo aomafi oti lo larokutu.
Odaju
No comments:
Post a Comment