Thursday, 17 December 2020

THE TRUTH OF IFA

 This is a benevolence univese om this ifa says:

A tree knot fears no rain

Cast Ifa for OLODUMARE AGOTUN

The ruler who created the well balance earth that cannot be broken 

When planning to establish a market on the water.

May all ire of the world locate us 

ASE EDUMARE

SPELL AGAINST EVEIL DOWERS. Back to sender spell.

Back to sender spell(Ayajo agbelepota todaju)
Use Iyereosun to imprint odu ika meji on any flat tray and chant this spell on it...
Arapanika
Okoko ni kase
Ikani kaja
Obiri biri ta won ji Awo osan
Eriwo ji wo Awo oru
Adanran ma dan olona ofun aasan
Ojiyan ogede niku omo Olofin
Opera lorugba epe waye
Awon mejejo yi lombe lotu Ife
Ise omo olomon  pipa je ni won n se
Orunmila gbera oni ohun nlo si Otu Ife
Won ni ki o  malo,
Oni  nitrori  kini
Won ni tori awon Awo mejejo ti mbe lotu Ife
To je pe ise omo olomo pipa je ni won nse
Orunmila ni ohun alo
Won ni ko  rubo
Orunmila rubo
Ebo fin ebo da
Orunmila gbera ode Otu Ife
Oni eyin Ife Odaye   e o  ji re bi ?
Oni Arapanika nko
Won ni ibi ini o gbe ka ,apa re ti kan oti ku
Oni Okoko ni kase nko?
Won ni ibi ti  gbe n ka ese, ese re ti kan otiku
Oni Obiribiri ta wonji wonji Awo osan nko?
Won ni otiba awo osan lo,o ti ku
Oni Eriwo jiwo awo oru nko?
Won ni Otiba Awo oru lo ,oti ku
Oni adarandan madan olofun aasan nko?
Won ni otipe aasan re ,ona ofun re ti be, oti ku
Oni ojiyan ogede ni kun omo olofin nko?
Won ni oti pe ogede re ,ikun re ti be, otiku
Oni Opera to ru igba epe waye nko?
Won ni oti se epe re ofa epe re to bolu lese otiku
Orunmila ni bi o ba se ni temi ( a o daruko wa)
Ibi tutu laba rinrin
Ibi tutu laba odundun
Ibi tutu laba tete
Ile igbin ki gbona mo igbin lara
Ki  gbogbo ohun t iota fe fi bami ja ki o da  tutu
Ki gbogbo ete buburu da pada  sori ota
After this spell,  you mixed it with a glass of water and drink. No evil spell will hurt you.

THE TRUTH OF IFA

 This is a benevolence univese om this ifa says: A tree knot fears no rain Cast Ifa for OLODUMARE AGOTUN The ruler who created the well bala...